Published 5 years ago in Other

Opomulero - Kay Wonder Ft. Dare Justified

  • 26
  • 3
  • 0
  • 3
  • 1
  • 0

Opomulero Mp3 Download by Kay Wonder Ft. Dare Justified

Lyrics

Opomulero Lyrics by Kay Wonder Ft. Dare Justified
Verse 1.
You are the pillar when all around me gives way,
(Gives way)
your word says in the world you shall have tribulations,
but be of good cheer I have overcome,
(Piller of my life,
e ma se, te o je nsonu,
opo aye mi mo dupe aye o gbe mi gbi..)2ce
Eyin ni mo ni ti mo fi n sako
.
Chorus..
Opomulero aye mi e ma se o/2ce
igi lehin ogba aye mi e ma se o,
ibi ti e mu mi de,
n ko le ro pe mo le de ibe,
E se oooo, ooooo, Ese oo
.
.
Verse 2.
Opomulero ooo, Baba, oh God,
You are the source of my strength when all hope is gone,
my salvation I will trust in You,
my life, my love, Lord you are my song,
(Piller of my life,
e ma se, te o je nsonu,
opo aye mi mo dupe aye o gbe mi gbi)2ce
Eyin ni mo ni ti mo fi n sako
.
.Chorus……

Verse 3.
Eyin le gbe mi ro,
ti e o je ki n jin si koto aye,
Eyin le ba wa se,
ina aye ko mama jo wa o,
iku ati ajakale arun to npa lojojumo ko ma ya ile wa,
Aye fe gba aso Lara wa, Eyin le da aso iyi bo wa Lara,
modupe ooo,
Alaasiri mi,
iyin ye yin ooo Jesu, Jesu,
Opomulero ayemi,
Eyin ni kokoro, {Kokoro}
kokoro, (kokoro) ti mo fi silekun ire,
Eyin ma ni, Kokoro (kokoro) Kokoro (kokoro) ti mo fi silekun agbara,
Eyin l’orin mi ti mo nko lojojumo, Ese oooo baba baba ooo Ese Opo,
.
Chorus……….
.
Piller of my life,
e ma se, te o je nsonu,
opo aye mi mo dupe aye o gbe mi mi,
.

(Eyin ni mo ni ti mo fi n sako)12x

00:37

amazing sir ..i love the song sir ..more Grace .

:
/ :

Queue

Clear